Level 2

66 words 0 ignored

Ready to learn       Ready to review

Ignore words

Check the boxes below to ignore/unignore words, then click save at the bottom. Ignored words will never appear in any learning session.

All None

Ignore?
àbúrò
younger sibling
ọjà
market
ilé wo ni o ra?
which house did you buy?
ṣọ̀ọ́ṣì
church
mùsíọ̀mù
museum
ilé-ìwé
school
ọ́fíìsi
office
kíláàsì
class
ilé-ìkàwé
library
ilé-ọkọ̀ ofurufú
airport
ilé àwọn ẹranko/ ogbà àwọn ẹranko
zoo
ẹ̀gbọ́n
older sibling
to come back/ return
sọ fún
to tell
lọ́la
tomorrow
ó dàárọ̀
goodnight
mi
my
(r)ẹ
your
(r)ẹ̀
his/her/its
wa
our
yín
your (pl/ honourific)
wọn
their
màá padà wá lọ́la
I will return tomorrow
màmá mi ti lọ sọ́jà
my mum has gone to the market
mo ti jẹun
I have eaten
to
in/at
dà/ níbo?
where?
Túnjí dà?/ Níbo ni Túnjí wà?
Where is Tunji?
(ẹ) káàárọ̀
good morning
(ẹ) káàsán
good afternoon
(ẹ) kúùrọ̀lẹ́
good evening
(ẹ) káalẹ́
good evening (late)
jókòó
to sit down
ọ̀rẹ́
friend
kò tọ́pẹ́
don't mention it/ you're welcome
díde
to stand up
kò burú
it's not bad/ it's OK
ọ̀gá
boss
ìwé
book
ẹ̀kọ́
lesson
ìfẹ́
love
(ẹ) pẹ̀lẹ́
greetings
to wake up
dúpẹ́
give thanks (to God)
sir
N kì í ọmọ ìlú Amẹ́ríkà ni mí/ ọmọ ìlú Amẹ́ríkà kó ni mí
I'm not American
ẹ́mi
emphatic pronoun "I"
kò/ ò
negative marker
pẹ́
to be late
ń lọ
is going
síbi iṣẹ́
to a place of work
ọmọ
child
mi
dialectical "mo"
iṣẹ́
work
ọjọ́
day
pẹ̀lú
with
àlàáfíà
peace
mo ti wẹ̀
I have taken a bath
mo wẹ̀ lánàá
I took a bath yesterday
mo máa wẹ̀ lọ́la
I will take a bath tomorrow
N kò ì tí ì wẹ̀
I haven't take a bath
N kò wẹ̀ lánàá
I didn't take a bath yesterday
N kò ní í wẹ̀ lọ́la
I won't take a bath tomorrow
ṣ'álàáfíà ni?
how are you doing?
ó wà
he/she is fine