Level 2 Level 4

54 words 0 ignored

Ready to learn       Ready to review

Ignore words

Check the boxes below to ignore/unignore words, then click save at the bottom. Ignored words will never appear in any learning session.

All None

Ignore?
mo gbọ́ èdè Yorùbá
I speak Yoruba
ṣé o gbọ́ èdè Gẹ̀ẹ́ṣi?
do you speak English?
èdè wo l'o gbọ́?
which language do you speak?
mo fẹ́ràn ajá
I like dogs
N kò fẹ́ràn ológbò
I don't like cats
edé
shrimps
mo fẹ́ràn láti jó
I like to dance
N kò fẹ́ràn láti sùn
I don't like to sleep
mutí
to drink (alcohol)
sọ̀rọ̀
to talk
mo fẹ́ sùn
I want to sleep
N kò fẹ́ pariwo
I don't want to make noise
lọ wo sinimá
to go to the cinema
kí ni o fẹ́ ṣe?
what do you want to do?
kí ni o fẹ́ràn láti ṣe?
what do you like to do?
kọrin
to sing
ilé oúnjẹ
restaurant
mo fẹ́ràn ìyàwó àti àwọn ọmọ mi gan an ni
I love my wife and children a lot
mo jẹun, mo sùn, mo sì ṣiṣé mi
I ate, I slept, and I did my work
èdè Sípáníísì
Spanish language
èdè Jámáànì
German language
èdè Òyìnbó/ Gẹ̀ẹ́sì
English language
Èko
Lagos
èdè Potogí
Portuguese language
èdè Faransé
French language
èdè Japaníìsì
Japanese language
èdè Ṣainíìsì
Chinese language
èdè Hébérù
Hebrew language
N kì í ọmọ ìlú Amẹ́ríkà ni mí/ ọmọ ìlú Amẹ́ríkà kó ni mí
I'm not American
ṣé èdè Sípáníísì le?
is Spanish difficult?
le
to be difficult
to look for, to come
that (relative clause marker)
rẹ́ǹtì
to rent
irú ilé wo ni o fẹ́?
what kind of house do you want?
to have
yàrá
bedroom
pálọ̀
living room
ilé ìdáná
kitchen
ibalùwẹ̀
bathroom
fúláàtì
flat
dára
good/nice
gbogbo
all
dárúkọ
to name
eélòó ni?
how much is it?
ẹgbẹ̀rún
a thousand
Náírà
Nigerian currency
fún
for
gba
to accept
l'oṣù
per month
dín
to be less
gbọdọ̀
to have to/ must
san
to pay
owó
money