Level 3

64 words 0 ignored

Ready to learn       Ready to review

Ignore words

Check the boxes below to ignore/unignore words, then click save at the bottom. Ignored words will never appear in any learning session.

All None

Ignore?
mo ń wá ilé tí mo lè rẹ́ǹtì
I'm looking for a house that I can rent
mo fẹ́ ilé tí ó ní yàrá kan
I want a house that has a bedroom
mo fẹ́ ilé tí ó tóbi
I want a house that is big
Sanjọ́ ní ìyàwó onírẹ̀lè
Sanjo has a humble wife
irú ilé wo ni o fẹ́?
what kind of house do you want?
ilé wo ni o ra?
which house did you buy?
ìwé wo ni Kẹ́mi ń kà?
which book is Kemi reading?
N kò mọ ìwé tí Kẹ́mi ń kà
I don't know the book that Kemi is reading
eélòó ni bàtà rẹ?
how much are your shoes?
ẹgbẹ̀run Náírà ni
it costs ₦1,000
eélòó ni Túnjí ra ọkọ̀ rẹ̀?
How much did Tunji buy his car for?
N kò mọ oye tí Túnjí ra ọkọ̀ rẹ̀
I don't know how much Tunji bought his car for
oókànlélógún
twenty-one
eéjìlélógún
twenty-two
ẹẹ́tàlélógún
twenty-three
ẹẹ́rìnlélógún
twenty-four
aárùnundínlọ́gbọ̀n
twenty-five
ẹẹ́rìndínlọ́gbọ̀n
twenty-six
ẹẹ́tàdínlọ́gbọ̀n
twenty-seven
eéjìdínlọ́gbọ̀n
twenty-eight
oókàndínlọ́gbọ̀n
twenty-nine
ọgbọ̀n
thirty
ogójì
fourty
àádọ́ta
fifty
ọgọ́ta
sixty
àádọ́rin
seventy
ọgọ́rin
eighty
àádọ́rùnún
ninety
ọgọ́rùnún
one hundred
igba
two hundred
ọ̀ọ́dúnrún
three hundred
irinwó
four hundred
ìwé dúdú
black book
ìwé funfun
white book
àga títóbi
big chair
àga kékeré
small chair
títóbi
big
tóbi
to be big
kéré
to be small
kékeré
small
ga
to be tall
gíga
tall
sanra
to be fat
sísanra
fat
kúrú
to be short
kúkúrú
short
Kẹ́mi kéré
Kemi is small
Kẹ́mi jẹ́ ènìyàn kékeré
Kemi is a small person
ọ̀jọ̀gbọ́n
professor
àwọn ọmọ rẹ̀ dára, wọn sì níwà jẹ́jẹ́
her children are good and gentle
ilé ìdáná rẹ̀ fẹ̀
her kitchen is spacious
ọkọ rẹ̀ kéré, ó sì wọ́n
her car is small and expensive
pálọ̀ rẹ̀ ní fèrèsè púpọ̀
her living room has many windows
ọkọ rẹ̀ jẹ́ olóòótọ̀, ó sì jẹ́ aláàánú
her husband is honest and caring
tuntun
new
fèrèsé
window
bẹ́ẹ̀dì
bed
kọ́bọ́ọ̀dù
cupboard
oúnjẹ
food
ọ̀bẹ
knife
fọ́ọ̀kì
fork
ṣíbí
spoon
àwo
plate
ife
cup